Gomina ana ni Ipinlẹ Eko, Bola Ahmed Tinubu ati Igbakeji Aare Yemi Oshinbajo ti ṣabewo ibanikedun si ile ijọsin aguda St Francis ni ilu Owo. Abẹwo naa lo waye lẹyin ikọlu tí awọn agbebon se si ile ...
Ile ẹjọ to ga ju lorilẹede Naijiria ni awọn yoo kede ọjọ ti wọn yoo gbe idajọ sita lori ẹjọ ti ijọba ipinlẹ Osun pe lati da agbẹjọro agba fun ijọba apapọ lọwọ duro lori sisan owo ijọba ibilẹ fun awọn ...